Jeremaya 46:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí ẹsẹ̀ wọn yá nílẹ̀ kò lè sálọ,bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ ogun kò lè sá àsálà.Ìhà àríwá, lẹ́bàá odò Yufurate, ni wọ́n tí fẹsẹ̀ kọ, tí wọ́n sì ṣubú.

Jeremaya 46

Jeremaya 46:5-9