Jeremaya 46:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ń dún bí ejò tí ó ń sálọ;nítorí pé àwọn ọ̀tá rẹ̀ ń bọ̀ tagbára tagbára,wọ́n ń kó àáké bọ̀ wá bá a,bí àwọn tí wọn ń gé igi.

Jeremaya 46

Jeremaya 46:12-26