Jeremaya 46:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ di ẹrù yín láti lọ sí ìgbèkùn, ẹ̀yin ará Ijipti!Nítorí pé Memfisi yóo di òkítì àlàpà,yóo di ahoro, kò sì ní sí ẹni tí yóo máa gbé ibẹ̀.

Jeremaya 46

Jeremaya 46:18-27