Jeremaya 46:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ẹ kéde ní Ijipti,ẹ polongo ní Migidoli, ní Memfisi ati ní Tapanhesi.Ẹ wí pé, ‘Ẹ gbáradì kí ẹ sì múra sílẹ̀,nítorí ogun yóo run yín yíká.

Jeremaya 46

Jeremaya 46:5-20