Jeremaya 46:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọjọ́ OLUWA àwọn ọmọ ogun ni ọjọ́ náà,ọjọ́ ẹ̀san, tí yóo gbẹ̀san ara rẹ̀ lára àwọn ọ̀tá rẹ̀.Idà rẹ̀ yóo pa àpatẹ́rùn, yóo sì mu ẹ̀jẹ̀ wọn ní àmuyó.Nítorí OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun ní ń rúbọ,ní ìhà àríwá, lẹ́bàá odò Yufurate.

Jeremaya 46

Jeremaya 46:1-15