Jeremaya 44:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wọn kò gbọ́ràn, wọn kò fetí sílẹ̀, wọn kò dáwọ́ ibi ṣíṣe dúró, wọn kò sì yé sun turari sí oriṣa mọ́.

Jeremaya 44

Jeremaya 44:1-11