Jeremaya 44:3 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí ibi tí wọ́n ṣe, wọ́n mú mi bínú nítorí pé wọ́n sun turari sí àwọn oriṣa tí àwọn tabi àwọn baba wọn kò mọ̀ rí, wọ́n sì ń sìn wọ́n.

Jeremaya 44

Jeremaya 44:1-8