Jeremaya 43:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Gbé òkúta ńláńlá lọ́wọ́, kí o bò wọ́n mọ́lẹ̀, níbi pèpéle tí ó wà lẹ́nu ọ̀nà ààfin Farao ní Tapanhesi, lójú àwọn ará Juda,

Jeremaya 43

Jeremaya 43:4-13