Jeremaya 43:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kó wọn lọ sí ilẹ̀ Ijipti, nítorí wọn kò fetí sí ọ̀rọ̀ OLUWA Ọlọrun wọn. Wọ́n lọ títí tí wọ́n fi dé Tapanhesi.

Jeremaya 43

Jeremaya 43:2-8