Jeremaya 43:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jeremaya parí gbogbo ọ̀rọ̀ tí OLUWA Ọlọrun wọn rán an sí gbogbo àwọn ará ìlú,

Jeremaya 43

Jeremaya 43:1-5