Jeremaya 42:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wí fún Jeremaya pé, “Kí OLUWA ṣe ẹlẹ́rìí òtítọ́ ati òdodo bí a kò bá ṣe gbogbo nǹkan tí OLUWA Ọlọrun bá ní kí o sọ fún wa.

Jeremaya 42

Jeremaya 42:3-12