Jeremaya 42:3 BIBELI MIMỌ (BM)

A fẹ́ kí OLUWA Ọlọrun rẹ lè fi ọ̀nà tí a óo gbà hàn wá, kí ó sọ ohun tí a óo ṣe fún wa.”

Jeremaya 42

Jeremaya 42:1-7