Jeremaya 42:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ti sọ ohun tí Ọlọrun wí fun yín lónìí, ṣugbọn ẹ kò tẹ̀lé ọ̀kan kan ninu ohun tí OLUWA Ọlọrun yín ní kí n sọ fun yín.

Jeremaya 42

Jeremaya 42:15-22