Jeremaya 42:16 BIBELI MIMỌ (BM)

ìyàn tí ẹ̀ ń bẹ̀rù yóo tẹ̀lé yín lọ sí Ijipti; ebi tí ẹ páyà rẹ̀ yóo gbá tẹ̀lé yín, ibẹ̀ ni ẹ óo sì kú sí.

Jeremaya 42

Jeremaya 42:15-22