Jeremaya 42:12 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo ṣàánú yín, n óo jẹ́ kí ó ṣàánú yín, kí ó sì jẹ́ kí ẹ máa gbé orí ilẹ̀ yín.’

Jeremaya 42

Jeremaya 42:8-15