Jeremaya 41:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n wọ ààrin ìlú, Iṣimaeli ọmọ Netanaya ati àwọn tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ pa wọ́n, wọ́n sì kó òkú wọn dà sí inú kòtò.

Jeremaya 41

Jeremaya 41:4-17