Jeremaya 41:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Iṣimaeli pa gbogbo àwọn Juu tí wọ́n wà pẹlu Gedalaya ní Misipa, ati gbogbo àwọn ọmọ ogun Kalidea tí wọ́n wà níbẹ̀.

Jeremaya 41

Jeremaya 41:1-4