Jeremaya 41:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Johanani, ọmọ Karea ati gbogbo àwọn olórí ogun tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ gbọ́ gbogbo iṣẹ́ ibi tí Iṣimaeli, ọmọ Netanaya ṣe,

Jeremaya 41

Jeremaya 41:10-18