Jeremaya 40:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Gedalaya bá búra fún àwọn ati àwọn eniyan wọn pé, “Ẹ má bẹ̀rù ati sin àwọn ará Kalidea. Ẹ máa gbé ilẹ̀ yìí, kí ẹ máa sin ọba Babiloni, yóo sì dára fun yín.

Jeremaya 40

Jeremaya 40:4-10