Jeremaya 40:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeremaya bá pada sọ́dọ̀ Gedalaya, ọmọ Ahikamu ní Misipa, ó sì ń gbé pẹlu rẹ̀ láàrin àwọn eniyan tí wọn kù ní ilẹ̀ náà.

Jeremaya 40

Jeremaya 40:1-14