Jeremaya 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbé àsíá sókè sí Sioni,pé kí wọn sá àsálà, kí wọn má ṣe dúró,nítorí mò ń mú ibi ati ìparun ńlá bọ̀ láti ìhà àríwá.

Jeremaya 4

Jeremaya 4:1-7