Jeremaya 4:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wò yíká, mo rí i pé gbogbo ilẹ̀ ọlọ́ràá ti di aṣálẹ̀,gbogbo ìlú sì ti di òkítì àlàpà níwájú OLUWA,nítorí ibinu ńlá rẹ̀.

Jeremaya 4

Jeremaya 4:23-30