Jeremaya 39:12 BIBELI MIMỌ (BM)

kí wọn mú Jeremaya, kí wọn tọ́jú rẹ̀ dáradára, kí wọn má pa á lára, ṣugbọn kí wọn ṣe ohunkohun tí ó bá ń fẹ́ fún un.

Jeremaya 39

Jeremaya 39:5-14