Jeremaya 39:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní oṣù kẹwaa, ọdún kẹsan-an ìjọba Sedekaya, ọba Juda, Nebukadinesari, ọba Babiloni, ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbógun ti Jerusalẹmu, wọ́n sì dótì í.

Jeremaya 39

Jeremaya 39:1-11