Jeremaya 38:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Sedekaya ọba bá kìlọ̀ fún Jeremaya pé, “Má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ gbogbo nǹkan tí a jọ sọ, o kò sì ní kú.

Jeremaya 38

Jeremaya 38:14-28