Jeremaya 37:7 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun Israẹli ní kí òun Jeremaya sọ fún ọba pé, àwọn ọmọ ogun Farao tí wọn wá ràn wọ́n lọ́wọ́ ti ń múra láti pada sí Ijipti, ilẹ̀ wọn.

Jeremaya 37

Jeremaya 37:6-15