Jeremaya 37:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeremaya jáde ní Jerusalẹmu ó fẹ́ lọ sí ilẹ̀ Bẹnjamini kí ó lọ gba ilẹ̀ rẹ̀ kan lọ́wọ́ àwọn eniyan tí wọ́n wà níbẹ̀.

Jeremaya 37

Jeremaya 37:6-16