Jeremaya 36:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeremaya bá pe Baruku ọmọ Neraya, ó sọ àwọn ọ̀rọ̀ tí OLUWA bá a sọ fún un, Baruku bá kọ wọ́n sinu ìwé kíká kan.

Jeremaya 36

Jeremaya 36:1-10