Jeremaya 36:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹ ẹ̀rù kò ba ọba tabi àwọn iranṣẹ rẹ̀ tí wọ́n gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí, wọn kò sì fa aṣọ wọn ya.

Jeremaya 36

Jeremaya 36:19-27