Jeremaya 35:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbé ìgò ọtí kalẹ̀ níwájú àwọn ọmọ Rekabu, mo kó ife tì í. Mo bá sọ fún wọn pé, “Ó yá, ẹ máa mu ọtí waini.”

Jeremaya 35

Jeremaya 35:1-11