Jeremaya 35:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Lọ sí ilé àwọn ọmọ Rekabu kí o bá wọn sọ̀rọ̀, mú wọn wá sinu ọ̀kan ninu àwọn yàrá tí ó wà ninu ilé OLUWA, kí o sì fi ọtí lọ̀ wọ́n.”

Jeremaya 35

Jeremaya 35:1-10