Jeremaya 34:7 BIBELI MIMỌ (BM)

ní àkókò tí àwọn ọmọ ogun ọba Babiloni gbógun ti Jerusalẹmu ati Lakiṣi ati Aseka, nítorí pé àwọn nìkan ni wọ́n ṣẹ́kù ninu àwọn ìlú olódi Juda.

Jeremaya 34

Jeremaya 34:3-11