Jeremaya 34:20 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fà wọ́n lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́ ati àwọn tí wọn ń wá ẹ̀mí wọn; òkú wọn yóo di oúnjẹ fún àwọn ẹyẹ ati àwọn ẹranko.

Jeremaya 34

Jeremaya 34:14-22