Jeremaya 34:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, Ọlọrun Israẹli ní, kí n lọ sọ fún Sedekaya, ọba Juda pé òun OLUWA ní, “Mo ṣetán tí n óo fi ìlú yìí lé ọba Babiloni lọ́wọ́; yóo sì dáná sun ún.

Jeremaya 34

Jeremaya 34:1-12