Jeremaya 34:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Èmi OLUWA Ọlọrun Israẹli bá àwọn baba ńlá yín dá majẹmu nígbà tí mo kó wọn jáde kúrò lóko ẹrú ní ilẹ̀ Ijipti, mo ní,

Jeremaya 34

Jeremaya 34:4-14