Jeremaya 33:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ ké pè mí, n óo sì da yín lóhùn; n óo sọ nǹkan ìjìnlẹ̀ ati ìyanu ńlá, tí ẹ kò mọ̀ tẹ́lẹ̀ fun yín.”

Jeremaya 33

Jeremaya 33:1-12