Jeremaya 33:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí OLUWA ní kò ní sí ìgbà kan, tí kò ní jẹ́ pé ọkunrin kan ní ilé Dafidi ni yóo máa jẹ́ ọba ní ilẹ̀ Israẹli,

Jeremaya 33

Jeremaya 33:15-21