Jeremaya 33:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀ lẹẹkeji, nígbà tí ó ṣì wà ní ẹ̀wọ̀n, ní àgbàlá àwọn tí ń ṣọ́ ààfin.

Jeremaya 33

Jeremaya 33:1-8