Jeremaya 32:7 BIBELI MIMỌ (BM)

‘Hanameli ọmọ Ṣalumu, arakunrin baba rẹ, yóo wá bá ọ pé kí o ra oko òun tí ó wà ní Anatoti, nítorí pé ìwọ ni ó tọ́ sí láti rà á pada.’

Jeremaya 32

Jeremaya 32:5-13