Jeremaya 32:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé àwọn ère wọn, tí ó jẹ́ ohun ìríra fun mi sinu ilé tí à ń fi orúkọ mi pè, kí wọ́n lè sọ ọ́ di ibi àìmọ́.

Jeremaya 32

Jeremaya 32:31-44