Jeremaya 32:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli sọ pé: wọn yóo tún máa ra ilẹ̀ ati oko ati ọgbà àjàrà ní ilẹ̀ yìí.’

Jeremaya 32

Jeremaya 32:12-23