Jeremaya 32:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo kọ ọ́ sinu ìwé, mo fi òǹtẹ̀ tẹ̀ ẹ́, mo pe àwọn eniyan láti ṣe ẹlẹ́rìí; mo sì fi òṣùnwọ̀n wọn fadaka náà.

Jeremaya 32

Jeremaya 32:7-18