Jeremaya 31:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Kàkà bẹ́ẹ̀ ẹni tí ó bá jẹ èso àjàrà kíkan,òun ni eyín yóo kan.Olukuluku ni yóo kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ara rẹ̀.

Jeremaya 31

Jeremaya 31:23-40