Jeremaya 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rò pé yóo pada tọ̀ mí wá, lẹ́yìn tí ó bá ṣe àgbèrè rẹ̀ tán ni; ṣugbọn kò pada; Juda arabinrin rẹ̀, alaiṣootọ sì rí i,

Jeremaya 3

Jeremaya 3:2-12