Jeremaya 3:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jẹ́ kí á dojúbolẹ̀ kí ìtìjú wa sì bò wá,nítorí pé a ti ṣẹ̀ sí OLUWA Ọlọrun wa;àtàwa, àtàwọn baba ńlá wa,a kò gbọ́ ti OLUWA Ọlọrun wa, láti ìgbà èwe wa títí di òní.”

Jeremaya 3

Jeremaya 3:17-25