Jeremaya 29:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa wá alaafia ìlú tí mo ko yín lọ, ẹ máa gbadura sí OLUWA fún un, nítorí pé ninu alaafia rẹ̀ ni ẹ̀yin náà yóo ti ní alaafia.

Jeremaya 29

Jeremaya 29:4-12