Jeremaya 29:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi ìwé náà rán Elasa, ọmọ Ṣafani ati Gemaraya, ọmọ Hilikaya: àwọn tí Sedekaya, ọba Juda, rán lọ sọ́dọ̀ Nebukadinesari, ọba Babiloni.

Jeremaya 29

Jeremaya 29:1-6