Jeremaya 29:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé wọn kò fetí sí ọ̀rọ̀ tí mo rán àwọn iranṣẹ mi, àwọn wolii, láti sọ fún wọn nígbà gbogbo.

Jeremaya 29

Jeremaya 29:14-22