Jeremaya 29:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa ti ọba tí ó jókòó lórí ìtẹ́ Dafidi, ati gbogbo àwọn tí ń gbé ìlú yìí, àní àwọn ará yín tí wọn kò ba yín lọ sí ìgbèkùn,

Jeremaya 29

Jeremaya 29:15-23