Jeremaya 28:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeremaya wolii bá sọ fún Hananaya pé, “Tẹ́tí sílẹ̀, Hananaya, OLUWA kò rán ọ níṣẹ́, o sì ń jẹ́ kí àwọn eniyan wọnyi gbẹ́kẹ̀lé irọ́.

Jeremaya 28

Jeremaya 28:14-17